Oh-oh, yea-yea, yeah
Barry tún tí dé eh, ah
('Long came Tuzi)
Tuzi 'pon the beat, oh-yea
Óyà now, tere na tere
Wọn gùn iyàn mí kéré
Kò kín ṣé ẹrú ọmọdé o
Kò lé yé wọn, na
Terere, na tere
Wọn gùn 'yàn mí kéré o
Kò kín ṣé ẹrú ọmọdé o
Kò lé ye wọn, na
O ga ra, o ga ra gan
O ski gban-gban
O gidi gan, oh-eh, o ga ra gan
O ski gban-gban, o gidi gan
O ga ra, o ga ra gan
O ski gban-gban
O gidi gan, oh-eh, o ga ra gan
O ski gban-gban, o gidi gan
Haters don't want you to be leading
Dey wanna see you falling
But if you gat God, gat God, oh-uh-oh, gat God
Àgbàdo inú ìgò, otí dá wo fojú f'adìẹ, yeah, yeah
Ẹní bà wó ìṣẹ́jú akàn, à pẹ létí omi
Óyà now, tere na tere
Wọn gùn iyàn mí kéré
Kò kín ṣé ẹrú ọmọdé o
(Kò ma-ma lé yé wọn) kò lé yé wọn, na
Terere, na tere
Wọn gùn 'yàn mí kéré o
Kò kín ṣé ẹrú ọmọdé o
Kò lé ye wọn, na
O ga ra, o ga ra gan
O ski gban-gban
O gidi gan, oh-eh, o ga ra gan
O ski gban-gban, o gidi gan
O ga ra, o ga ra gan
O ski gban-gban, o gidi gan
Oh-eh, o gara gan
O ski gban-gban, o gidi, eh-eh
Ah, b'omi ṣé wọnú agbọ'n, kò s'ẹní tó ye, ah-ah, ah
Ìṣẹ' Olúwa àwa má ridi ní
Bí mo ṣé sọ tẹ'lẹ'
B'omi òkun ṣé ńrú, kò má s'ẹní to ye láyé
Wey God dey do Him wonder, nobody knows
Óyà now, tere na tere
Wọn gùn 'yàn mí kéré
Kò kín ṣé ẹrú ọmọdé o
Kò lé yé wọn láyé sẹ
Terere, na tere
Wọn gùn iyàn mí kéré o
Kò kín ṣé ẹrú ọmọdé o
Kò lé ye wọn, na
O ga ra, o ga ra gan
O ski gban-gban
O gidi gan, oh-eh, o ga ra gan
O ski gban-gban, o gidi gan
O ga ra, o ga ra gan
O ski gban-gban, o gidi gan
Oh-eh, o ga ra gan
O ski gban-gban, o gidi-
Kò má sí òun t'Ọlọrun o lé ṣe
(Tee Y mix)
Ayé mí o sí lọwọ anybody
Kòmá sí lọwọ anybody
Bàbá lo ní final say, ṣé ẹ gbo? (Oh, na)
Ẹní tò bá bẹ, ó má s'ara sẹ
('Long came Tuzi)
Поcмотреть все песни артиста