Yeah-yeah, ah-ahh, ah
Ṣijú anu wo mí oh, Elédùmarè, Bàbá
Oh-ahh-ayy, ah-ayy
Ayy, na-na (Ice)
T'ọmọdé, t'àgbàlagbà, lo w'ojú réré rẹ
Ukwu-ukwu ku, w'ojú réré rẹ
Ẹni tó l'ọwọ' àti ẹni o ní, wọn w'ojú réré rẹ
Kos'ohun t'ole ṣe, kos'ohun to poju fún o láti ṣe
Ìwọ ṣa l'Ọba, kosi Ọba mí rán lẹ'yìn rẹ, lẹ'yìn rẹ oh
Kosi ẹlòmíràn, Bàbá bless me, yeah-oh
Bàbá, jọ'wọ', bless me, ah-ah
Olu ọrùn, níbo l'ojú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
À fẹ reeti re oh, Bàbá
Olu ọrùn, yeah, níbo l'ojú rẹ wà? Ayy o
À fẹ reeti rẹ oh
Olu ọrùn, níbo l'ojú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
À fẹ reeti re oh, Bàbá
Olu ọrùn, yeah, níbo l'ojú rẹ wà? Ayy o
À fe reeti rẹ oh
Ìwọ lo s'ọkọ fún opó
Ìwo ní Bàbá 'láì ní bàbá, ayy, oh-ah
Ìwọ ní má pé tí wàhálà bá dé
Kosi ẹlòmíràn àfi ìwọ, oh-oh, àfi ìwọ
Maje k'ojú tí mí
T'ọmọdé, t'àgbàlagbà lọ w'ojú réré rẹ
Ukwu-ukwu, ku, gan w'ojú réré rẹ
Ẹni tó l'ọ'wọ' àti ẹni o ní, wón w'ojú réré rẹ
Kos'ohun t'ole ṣe, kos'ohun tó poju fún o làti ṣe
Ìwọ ṣa l'Ọba, kosi Ọba mí rán lẹ'yìn rẹ, lẹ'yìn rẹ oh
Kosi ẹlòmíràn, Bàbá bless me, yeah-oh (nibo l'oju re wa? Yeah)
Bàbá, jọ'wọ', bless me, ah-ah
Olu ọrùn, níbo l'ójú rè wà? Ayy-ayy, ayy
À fẹ reeti rè oh, Bàbá
Olu ọrùn, yeah, níbo l'ójú rè wà? Ayy o
À fẹ reeti rè oh
Olu ọrùn, níbo l'ojú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
À fẹ reeti rẹ oh, Bàbá
Olu ọrùn, yeah, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy o
À fẹ reeti rẹ oh
Ẹni o l'ójú, ó fún l'ójú k'ofi rí rán
Ẹni o l'ẹnu, iṣe lè fún l'ẹnu k'ofi ṣ'òro
Ẹni o létí, ẹ fún létí k'ofi gbọ́ràn
Ẹni o l'órí rò, niṣe lẹ yá l'ọpọlọ
T'ọmọdé, t'àgbàlagbà lọ w'ojú réré rẹ
Ukwu-ukwu, ku, w'oju rere rẹ
Ẹni tó l'ọ'wọ' àti ẹni o ní, wón w'ojú réré rẹ
Kos'ohun t'ole ṣe, kos'ohun tó poju fún o láti ṣe
Ìwo ṣa l'Ọba, kosi Ọba mí ràn lẹ'yìn rẹ, lẹ'yìn rẹ oh
Kosi ẹlòmíràn, Bàbá bless me, yeah-oh (níbo l'ójú rè wà o? Eh)
Bàbá, jọ'wọ', bless me, ah-ah
Olu ọrùn, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
À fẹ reeti rẹ oh, Bàbá
Olu ọrùn, yeah, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy o
À fẹ reeti rẹ oh
Olu ọrùn, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
À fẹ reeti rẹ oh, Bàbá
Olu ọrùn, yeah, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy o
À fẹ reeti rẹ oh
Daddy, with you-'ou-'ou
Nothing is impossible, (ehn-ehn)
Daddy, you're powerful, (ehn-ehn, oh)
Nothing wey you no fit do
Ah-ayy, ayy
Поcмотреть все песни артиста