Ohh, eh, ah-eh
O rí pé, ayọńbọ l'òwúrò, ehh
♪
(Ice)
Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọńbọ l'òwúrò
T'obà r'ọwọ Olùwà nílé àyé rẹ
Ṣá tí mo wípé, ayọńbọ l'òwúrò, ye o
Ayọńbọ wa l'òwúrò oo, eh
Ayọńbọ wa l'òwúrò, eh
Ẹkùn le pẹ títì d'alẹ, ṣùgbọ'n ayọńbọ l'òwúrò
I say joy in the morning
Joy every day, that's all I see
Ohh, eh, Baba God, na Your light dey shine on me like this o
I no know how to thank You, uh-yea, yea-yea
Every day, burst my brain every day, make me want me to dey pray
Na you be my God, yea, Baba oh-ye
Na You dey bless the person wey no get, Bàbá noni
Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọńbọ l'òwúrò, ye o
T'obà r'ọwọ Olùwà nílé àyé rẹ
Ṣá tí mo wípé, ayọńbọ l'òwúrò, ye o
Ayọńbọ wa l'òwúrò uh, eh
Ayọńbọ wa l'òwúrò, e
Ẹkùn le pẹ títì d'alẹ, ṣùgbọ'n ayọńbọ l'òwúrò
Hmm, na You be the God of Promise
Na You be the God of Covenant o
The promise wey You do for my life o, májẹ kó kọjá mí
Na You, na You o, na only You o
Ìwọ ṣa lo ń ṣọmi o, Ìwọ ṣa lo ńṣe òun gbogbo eh
Burst my brain every day (every day), make me want to dey pray
Na you be my God, yea, Baba oh-ye
Na You dey bless the person wey no get, Baba loni
Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọńbọ l'òwúrò, ye o
T'obà r'ọwọ Olùwà nílé àyé rẹ
Ṣá tí mo wípé, ayọńbọ l'òwúrò, ye
Ayọńbọ wa l'òwúrò oo, eh
Ayọńbọ wa l'òwúrò, e
Ẹkùn le pẹ títì d'alẹ, ṣùgbọ'n ayọńbọ l'òwúrò
Eh-eh-eh-eh, uh-oh (Ice)
Ayọńbọ l'òwúrò
Yea-yea-yea-oh-uh-oh-oh
Ice, ayọńbọ l'òwúrò
Поcмотреть все песни артиста