Kishore Kumar Hits

Barry Jhay - My Father My father текст песни

Исполнитель: Barry Jhay

альбом: Barry Back 2


Oh-oh-ohhh-oh-oh-ohhh-
Oh-oh-ohhh-oh-oh-ohhh, ye-ye
(Mad-Madaroad)
Oh-oh-ohhh-yea-yea-ohhh-
Ye-ye, ye
Say, I don't force it
I just let the Spirit lead, 'cause I know
Yes, I know You are with me all the way
My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹmilẹ o, ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
Ẹlẹwa Ògo (hm), Àdàbà Mímọ, jọwọ, bale mí o oh-ohh (emi ọmọ rẹ ree)
Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe
Ẹmí-Mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo
Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
Má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹlẹ'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, ye, re o
Má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkelẹ'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yeah-oh
Ìrìn yí mọọ, má lọ lofo, ní mo ṣe d'ẹsẹ' Ọlọ́run mí mú o, uh
(Ní mo ṣe gbà Ọlọ́run mí mú ṣinṣin)
Bí Olùwà ṣe ń sọla ìyẹn nínú ọlá àt'ayo
Bẹ ní yí o tún ṣògo, ohh, Ọlọrun mí ògo
My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹmilẹ o, ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
Ẹlẹwa Ògo (hm), Àdàbà Mímọ, jọwọ, bale mí o oh-ohh (emi ọmọ rẹ ree)
Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe
Ẹmí-Mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo
Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
Má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹlẹ'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, ye, re o
Má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkelẹ'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yeah-oh
(Sunshine on the mix)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Ire

2023 · сингл

Похожие исполнители

Otega

Исполнитель

Kashy

Исполнитель

Ayox

Исполнитель

Tia

Исполнитель

Lyta

Исполнитель