Kishore Kumar Hits

Ty Bello - Logan Ti O De текст песни

Исполнитель: Ty Bello

альбом: Logan Ti O De


Emi mo oun oju mi tiri
Mo mo oun eti mi ti gbo
Mo oun oju mi tiri
Mo mo oun eti mi ti gbo
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala
Aiye mi le to
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala
Aiye mi le to
Mo mo oun aiye ma ti wi
Mo mo oun eyan ma ti so
Won ti pe wa ni agan ri
Boya won ti pewa lo'olosi ri
Sugbon, Logan ti o de o Olugbala, aye e le to
Sugbon, Logan ti o de o Olugbala, aye e le to
Aye to ti daru tele tele o
Logan ti o de
Oro ti eniyan ti fi s'alufani re
Logan ti o de
Oro ti ko dara ta ti so si o
Logan ti o de
Oruko ti kin se tire ta ti pe o
Logan ti o de
Ani logan ti o de o Olugbala aye e le to
Logan ti o de o Olugbala
Aye e le to
Logan ti Jesu de o Olugbala
L'aye e le to
Ko s'oruko t'aye o le pe ni
Wa ma peni l'agan l'ona gbo gbo
Bo ba lowo lowo agan n
Bo ba bi mo o agan ni
Bo ba tegba ko dagba agan lo je
Sugbon logan ti o de
Sope logan ti o de
Ani logan ti o de, lesekese
Logan ti o de
Ahah, logan ti o de o Olugbala
L'aye e le to
Logan ti o de o Olugbala
L'aye e le to
Instantly lo'n je be
Bo se n debe
Won de yi oruko pada
Logan ti o de, eheheh logan ti o de
Eyin ta pe l'agan e ma so wi pe
Logan ti o de
Awon ta ti fi oruko aburu pe ni'le won yi
Logan ti o de
Ani logan ti o de o Olugbala, l'aye mi le to
Logan ti o de o Olugbala
L'aye mi le to
Ani eheh, logan ti o de o Olugbala
L'aye mi le to
Ani, logan ti o de o aseda
L'aye mi le to
Ani, logan ti o de o Olorun o
L'aye mi le to
Irawo owuro omo Mary yo sinu oro mi, l'aye mi le to
Ah, alagbara ni Shiloh loba ran ti mi si rere, l'aye mi le to
Enu mi wa kun fu eri o gbogbo, l'aye mi le to
Aye mi gba iyipada otun o logan to de, l'aye mi le to
Aye mi ba leto l'ota ba wo Iran mi, l'aye mi le to
Aye mi le to lo ta bawo Iran mi, l'aye mi le to
Ota kaworo, enu won gbe tan lori oju kan, l'aye mi le to
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l'aye mi le to
Thank you Lord Jesus for all you've done

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители