Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Omoagba текст песни

Исполнитель: Beautiful Nubia

альбом: Several More Tales from a Small Room


Omo agba, seb'oti de'le owo
Ma ma se s'iwa hu
Ma jeun womuwomu bi alejo
Omo agba, a lo ti wo'le ola o
Ma ma se s'iwa hu
Ma te'le jaujau bi ajeji

Eni abi ire kii b'inu odi
Oni'wa tutu, eni ire ni
Omoluabi abani t'omo o
Atun ilu to, omo oko
Omo agba, seb'oti de'le owo
Ma ma se s'iwa hu
Ma jeun womuwomu bi alejo
Omo agba, a lo ti de'le agbara o
Ma ma se s'iwa hu
Ma te'le jaujau bi ajeji

Eni e to fun, won nbe l'ode o
Awon yen n w'oju olorun l'oke oba ni
Eni o i ba ti se won po n'ita
Awon yen n w'oju eledumare ko dahun
Omo agba, seb'oti de'le owo
Ma maa s'iwa hu
Ma jeun womuwomu bi alejo
Omo agba, a lo ti wo'le ola o
Ma maa se s'iwa hu
Ma te'le JauJau bi ajeji

Ma jeun womuwomu bi alejo (ye o)
Omo agba

Ma te'le JauJau bi ajeji (ye o)
Omo agba

Ma jeun womuwomu bi alejo (ye o)
Omo agba

Ma te'le JauJau bi ajeji (ye o)
Omo agba

Ma jeun womuwomu bi alejo (ye o)
Omo agba

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель

Darey

Исполнитель