Igbeyin lo ju o, k'o mo
Sebi 'bere, iyen ki s'onise
Ka f'ara s'ise o to jare
Ka f'ogbon si o, pelu suru
A ti ru'bo oju, a s'oro didun, f'eni t'o nworan o
Ka ma ma ko'se
Awa ti d'omi siwaju, ka le te'le tutu
Ka ma se r'oun ti o koja emi wa
Sa ma gb'ese lokankan olufe
Ojo ti da wayi, ko s'abata l'ona
Fu'rugbin s'apa otun ati s'owo osi
Oni ojo ibukun, ero ni gbeyin iji
Ya mu'ra ode, olufe
Ko s'oun t'o nbo wa to le si o ni'po
Jijo re s'egbe otun ati s'apa osi
Oni ojo idunnu, ojo ni gbeyin erun
Igboya ni o gbe wa, k'o mo
Oniberu, awon yen o ni le duro
Ka be Olu-Aje o to jare
Ka s'ise lo ju, lai s'awawi
A ti ru'bo oju, a s'oro didun, f'eni t'o nworan o
Ka ma ma ko'se
Awa ti d'omi siwaju, ka le te'le tutu
Ka ma se r'oun ti o koja emi wa
Sa ma gb'ese lokankan olufe
Ojo ti da wayi, ko s'abata l'ona
Fu'rugbin s'apa otun ati s'owo osi
Oni ojo ibukun, ero ni gbeyin iji
Ya mu'ra ode, olufe
Ko s'oun t'o nbo wa to le si o ni'po
Jijo re s'egbe otun ati s'apa osi
Oni ojo idunnu, ojo ni gbeyin erun
♪
Ah aaaaah
Ah aaaaah
A ti ru'bo oju, a s'oro didun, f'eni t'o nworan o
Ka ma ma ko'se
Awa ti d'omi siwaju, ka le te'le tutu
Ka ma se r'oun ti o koja emi wa
Sa ma gb'ese lokankan olufe
Ojo ti da wayi, ko s'abata l'ona
Fu'rugbin s'apa otun ati s'owo osi
Oni ojo ibukun, ero ni gbeyin iji
Ya mu'ra ode, olufe
Ko s'oun t'o nbo wa to le si o ni'po
Jijo re s'egbe otun ati s'apa osi
Oni ojo idunnu, ojo ni gbeyin erun
Ya mu'ra ode, ode
Mu'ra ode, ode
Mu'ra ode, ode
Поcмотреть все песни артиста