Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Ohun Merin текст песни

Исполнитель: Beautiful Nubia

альбом: Several More Tales from a Small Room


Ará mo gbo oro kan oh
L'enu iye mi àgbà
Won l'afeni fe ire, won o sopọ laye
Àgbà ju owo yen se ohun la fi n soya
Ka rin ka po ni so kan oh
Ani mo gbo hun todun l'enu iye mi àgbà
Won l'eni ti ọ jẹ oyin àpáta kíì wò ẹnu ake
Ki ma I se oju boro laa gbọmọ ekuro
Ore mi gbera nde
You stand for your right
I stand for mine
Everyone must play his part
We ask for the truth
And demand for justice
Only love will set us free
Mo ma gbo ohun to dun lenu iye mi àgbà
Won l'ohun mẹrin ni nbe o, ti oje ayé ọ gun
Ayi s'otitọ (oun bẹ ni be)
Ayi ni itẹlọrun (oun be ni bẹ)
Imo temi nikan (oun be ni bẹ)
Ote, iyen bẹ ni be

Ará mo gbo oro kan oh
L'enu baba oni irun gbọn
Won imo iwe yen ose pàtàkì o jọ ju
Súgbon ogbon awọn àgbà ṣe yen ni isembaiye
Ko se fi ọwọ ro seyin laiye laiye
Àní mo gbohùn to dun
L'enu aṣabi olomo wẹwẹ
Woni abáni se yen oh
Won opo bi aba ni lo gba
Akinkoju ẹrọ ra ogbon loro yi ọ gba oh
Ojo ominira nbọ kankan
You stand for your right
And I stand for mine
Everyone must play his part
We ask for the truth
And demand for justice, only love will set us free

You stand for your right
I stand for mine
Everyone must play his part
We ask for the truth
And demand for justice, only love will set us free
Mo ma gbó'hun to dun (ohun to dun)
L'ẹnu iye mi àgbà
Won lohun mẹrin nbe oh
Ti oje ayé o gun
Ayi s'otitọ (oun be ni bẹ)
Ayi n'itẹ lọrùn (oun bẹ ni bẹ)
Imoteni nikan (oun bẹ ni bẹ)
Ote, iyen nbe ni bẹ

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель

Darey

Исполнитель