Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Ikore текст песни

Исполнитель: Beautiful Nubia

альбом: Lord of Letters


Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o, ẹ kú àbò, ẹmá kú àbò, ẹ kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ
There is a season to be out in the fields
Many months of back-breaking work
There is another season for bountiful harvest
And that is why we have gathered to celebrate, yea-eyeah
Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹmá kú àbò, ẹ kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ
Father was the knower who taught us everything
Mother was the pillar who gave us strength
All hands to the plough, we weathered many storms
And that is why we are happy to celebrate, yeah-e, ay-ay-ay
Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹmá kú àbò, ẹ kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ

The drums are resounding, voices raised in song
Young maidens clapping, wiggling waists
I have only eyes for you, my sweet darling
You glow so bright in the moonlight
Àní, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹmá kú àbò, ẹ kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ'
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ'
Àní, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹmá kú àbò, ẹ kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
Ẹní tó ń bọ' l'ókéré, a kí yín (ẹ kú àbò o)
Ẹní to ń bẹ ni'joko a kí yín o (ẹ kú àbò o)
A kú ìjo, a má kú ayọ', a kí yìn (ẹ kú àbò o)
Ọdọ-'mọde pel'àgbàlagbà, a kí yín (ẹ kú àbò o)
Ìyá Ẹgbẹ', Bàbá Ètò, a kí yín o (ẹ kú àbò o)
Àní, kú ìjo, a má kú ayọ', a kí yìn (ẹ kú àbò o)
Tẹ̀rín-tẹrìn pélọyaya, a kí yìn o (ẹ kú àbò o)
Ẹní s'ìṣẹ ye kò gbádùn, a má ki yìn (ẹ kú àbò o)
(Ẹ kú àbò o)
(Ẹ kú àbò o)
(Ẹ kú àbò o)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель

Darey

Исполнитель