Orisimeta eda laa pade arinrinajo Orisimeta eda laa kan l'ode aye eni're Eni ti o gbe ni soke, iyen a tan bi ojo tuntun Eni ti o b'eni kedun kii jina si'bi ofo Eni ti o loso idena, iyen ki ma i f'oju han ni K'inu re ma so e eni're K'owo e ma ri're ati ibukun Kori e gbe e de bi ayo, onu ni Baba wi Ase gun! Orisimeta eda laa pade arinrinajo Orisimeta eda laa kan l'ode aye eni're Eni ti o gbe ni pon s'eyin g'oke laikun lai s'awawi Eni ti o ko ni l'ese bi itakun arapalakiri Eni ti o wo ni s'ogbun ijogbo, agbara olorikunkun K'inu re ma so e eni're K'owo e ma ri're ati ibukun Kori e gbe e de bi ayo, onu ni Baba wi Ase gun! ♪ Orisimeta eda laa pade arinrinajo Orisimeta eda laa kan l'ode aye eni're Eni ti o ba ni so'ro tutu, a fi'nu han ni Eni ti o to ni s'ona iya, oun ke a gba 'bomiran Eni ti o ba ni se po, a gb'eyin se yeye eni K'inu re ma so e eni're K'owo e ma ri're ati ibukun Kori e gbe e de bi ayo, onu ni Baba wi Ase gun! K'inu re ma so e eni're K'owo e ma ri're ati ibukun Kori e gbe e de bi ayo, oun ni Baba wi Ase gun! K'inu re ma so e eni're K'owo e ma ri're ati ibukun Kori e gbe e de bi ayo, oun ni Baba wi Ase gun!