Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - A O Dide текст песни

Исполнитель: Beautiful Nubia

альбом: Lord of Letters


Alágbára ńwùga, kò ṣe 'fura
O l'òun l'ọ̀gá ìgbà
A f'ọwọ ọlá gbà ní tẹ'yókù mọ'lẹ'
Kò má ṣ'ení tó-tó f'ohùn
Alágbára ń kó ní l'áyà jẹ
O l'òun l'ọ̀gá àsìkò
Ìkà ẹlẹ́nu eewọ af'ọrọ fa'ní l'etí ya
Kò má ṣ'ení tó-tó fohùn
Alakọri o mọ wípé a o dídé o
Wípé à o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé à o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, à o dídé o
Kò mọ wípé a o dídé o
Wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, ta o dídé o

Ẹgbá mẹ́rìnlá l'oúnjẹ òwúrò
Iko méjìlá ni t'ọ'sán o
Ẹnì to kàn lo mọ, kò ní ṣe'rú ẹ mọ
Ípàṣán ẹlẹrújẹjẹ
Ní'lé wọn tí kò ní l'ọrọ lo
L'odò, a o rí'bí sọrọ
Àgbà ń d'orikodò ń ronú o
Kò má sẹni to jẹ f'ohùn
Alakọri o mọ wípé a o dídé o
Wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, a o dídé o
Àní, kò mọ wípé a o dídé o
Wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, ta o dídé o

K'oníkálukú gbéra ni'lẹ
Òní l'ọjọ' ìtúsílẹ̀
A fẹ ko're jáde, ìtura mà dé o
Ọnà lá, kà'yé wá tóóró
Ẹ jọwọ, ẹ sọ fún wọn wípé a o dídé o
Wípé à o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé à o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, à o dídé o
Ẹ sọ fún wọn wípé a o dídé o
Wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, à o dídé o
À o dídé o
À o dídé o
À o dídé pọ
À o dídé o
À o dídé o
À o dídé o
À o dídé pọ
(Ọjọ' dé tàn) a o dídé o
À o dídé o
À o dídé o
À o dídé-

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель

Darey

Исполнитель