Oluwa Oni Dehin lehin mi o Iwo ni mo gbojule, iwo ni mo fehinti Lati owuro titi da le Oluwa Oni Dehin lehin mi ooo Bi mo ba ji, Bi mo ji owuro Ma kaleluya patewo yin baba logo ooo Maa mura fun se Ise oojo mi Tin ba ti jade ma kale luya fun baba Baba bami se Onise iyanu Titi ayeraiye Oo, ni mio ma yin ooo baba