Kishore Kumar Hits

C&S Church Movement - Assurance, Pt. 2 текст песни

Исполнитель: C&S Church Movement

альбом: Assurance


Lo kede Ayo, Oluwa ran o
Bi agutan s'arin ikoko aiye
Gbe fitila iyin rere
(Percussion display)
Dide tan mole ayo
Ogo Oluwa yio yo lara re
Wi fun Jesu wipe emi niyin ran mi
Iroyin ayo so t'irapada f'araye
Lead 1
Iroyin ayo ni fun gbogbo eda
Wipe Jesu joba lori gbogbo aiye
A o da o nide, a o fi ayo de o lade
Jesu yio yo si o pelu owo itura re
Lead 2
Ore faramo Jesu
Ojo... aiye yi nlo bi afefe
T nrekoja, to ko si yi pada rara
Iba dara ko pese fun le re loke orun
Gboju re soke wo rawo didan
To nso t'ife Olorun
Wipe bo ti wu kiji aiye le to
Owo agbara Oluwa yio da duro
Gbo Ohun alore, ji ara ji
Jesu ma fere de, ji ara ji
Omo oru ki nsun
Omo imole leyin
Ti nyin logo didan, ji ara ji
Ji, iwo okan mi
Ji o, ko orin iyin
Korin ayo, gbohun ayo s'oke o
Si Baba, eleruniyin
E gbe laruge, e so t'ife re si eniyan
Bi Baba ba nbinu, aiye iba ti f'aya
O fi omo bibi re s'etutu f'ese wa
Se rere o omo, Baba nreti re
(Interlude... Jesu npe wa losan loru)
Oro Oluwa lo nwipe
Awon to gbekele Oluwa
Yio dabi oke sioni to duro lailai
A o tun agbara mi se
Bi mo sare ko ni re mi
Wun o rin are kan ko ni si
A o b'omirin irugbin mi
Wun o fi iye fo bi idi
Ninu ayo owo agbara igbala
(Percussion Display)
Call: Ta lo nkan lekun okan mi
Res: Jesu Alagbara, Jesu Atobiju
Call: Ta lo wo mi laso iye
Oba to segun iku
Alade Alafia
O di igbekun ni igbekun lo
O gba ebun rere fun mi o
O mba mi gbe nigbagbogbo, mo gbo ohun re nitosi o
Amona at'oluto mi loje
Ti ko ni f'asiri mi han
O nfi ilera fun okan mi
Mo fe O edidi ife
O f'ounje iye bo mi
O nfun mi l'omi iye mu
Ta lo le mu mi rerin ayo, To mba mi s'ore otito
Alagbawi mi loke o, wa de mi lade ogo
End

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители