Olo MI onitemi Oremi ololufe Oju kan sha lada ni Lola Oluwa ko so oun ti o ya wa Olo MI Oni temi Ore MI Ololufe Ni o la oluwa ko si oun ti o ya wa Mo ri oun to dun mo re ni Keji me Giri giri loin se mi, got butterfly in my belle Kori kosun ko je ko mu E ma bawi o Oro Ife laye bi adanwo ni Iru omo ti mo fe Oun be Lara re Baby gbo oruko mi o ba e lewa mu Mo fe ba e da ru gbo Mo fe ba e dale Iwo ni mo fe ma ji ri Lo jojumo aiye mi Olo mi sweetheart oni temi Ore mi, ololufe Oju kan sha lada ni Lola oluwa wa ko si oun ti o ya wa E olo mi, onitemi Ore mi ololufe Oju kan lada ti o ri e ni Lola oluwa ko si oun ti o ya wa I found a good thing Thing from above I got that feeling The same a touch of love I've stay so long But Ife wa mi ri Now that you are here