Suurulere o Aaaaaaaooo E sun mo 'bi O ya! E farabale k'a sere o E farabale k'a sere oloyin E farabale k'a sere o E farabale k'a sere oloyin o E je k'a mu 'joko o K'a mu 'joko o, k'a so 'tan Itan t'o ma m'ogbon wa O ye k'a lowo K'a lowo, k'a lola Ra moto repete K'a ni'le lori Sugbon k'a tun ni suuru Suurulere o Oooooo Eeeeeh hey! O ni baba kan Baba olowo olola Baba motors, baba petroleum MD/CEO ile-ise repete Popular Jingo, philanthropist ni baba O se f'onile, o tun se f'alejo Oba orun eyi ni mo fe Ki n lowo, ki n m'owo, ki n tun m'Olorun Oh yes, k'oro mi le d'ayo o K'oro mi le d'ayo o Ah oh yee o, k'oro mi le d'ayo o K'oro mi le d'ayo o Ah oh yee o, k'oro mi le d'ayo o Owo f'eju m'omo o Owo f'eju m'omo o eeeeh Owo f'eju m'omo baba o Owo f'eju m'omo o Owo f'eju m'omo o eeeeh Owo f'eju m'omo o Owo f'eju m'omo o aaaah Ikun n j'ogede, ikun n re'di mole Ikun o mo p'ohun to dun o (ko mo p'ohun to dun o) Lo n pa'ni laye o Ki lomo f'owo se o eeeeh? (Ooo eeeh) Ki lomo f'owo se a eeeeh? (Aaa eeeh) Pansaga paraga E fun mi ni ti'bi Onijekuje Ikun o mo p'ohun to dun o (ko mo p'ohun to dun o) Lo n pa'ni laye o Baa o ba mo 'bi a mi re Se b'aa mo bi a ti wa Baa o ba mo 'bi a mi re Se b'aa mo bi a ti wa Omo eni i buru k'a fi f'ekun pa o Baba gba mi o, mo ma yege Mo ma yege (Iyeeee mo yege) Iyeee iyeeee mo yege e (Iyeeee mo yege) Baba gba mi o (Iba mi ma seun o) Iba mi ma seun o (Iba mi ma seun o) Iba iba iba mi ma seun o (Iba mi ma seun o) Aye oniyo re o (maa yo o) Ma yo, ma yo, ma yo, ma yo, ma yo (maa yo o) Aye oniyo re o (maa yo o) Ma yo, ma yo, ma yo, ma yo, ma yo (maa yo o) Aye oniyo re o (maa yo o)