Lorí òkè calvary o Lorí òkè calvary o Lori igi agbelebu Wan kan Jésù mọ'gi o Wan tutọ sí lára o Wan de ni ade ẹgún Nitori ẹsẹ t'emi Nitori ẹsẹ ti ẹ B'iya ọrún ṣe pọ tó, ko dakẹ adura O n bẹbẹ fún wa "Baba d'áríjì wan, wan o mọ ùn wan ṣe" Lorí òkè calvary o (Ẹni kín gbọ) Lorí òkè calvary o Lori igi agbelebu Wan kan Jésù mọ'gi o Wan tutọ sí lára o Wan de ni ade ẹgún Nitori ẹsẹ t'emi Nitori ẹsẹ ti ẹ B'iya ọrun ṣe pọ tó, k o dakẹ adura O n bẹbẹ fún wa "Baba d'áríjì wan, wan o mọ ùn wan ṣe" Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé Nibi ti ibi aye ko le de Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé Nibi ti ibi aye ko le de Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ Apata ayérayé ṣe ibi isadi mi Jẹ kí omi owẹjẹ Ko ṣàn lati ira rẹ Ṣe iwosan f'ẹsẹ mi Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé Nibi ti ibi aye ko le de Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé Nibi ti ibi aye ko le de Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ Apata ayérayé ṣe ibi isadi mi Jẹ kí omi owẹjẹ Ko ṣàn lati ira rẹ Ṣe iwosan f'ẹsẹ mi