Ode Le alaga, ode Le alaga Oyele mori re, oyele mori re wale Ode Le alaga, ode Le alaga Oyele mori re, oyele mori re Ode Le alaga, ode Le alaga Oyele mori re, oyele mori re wale Ode Le alaga, ode Le alaga Oyele mori re, oyele mori re Ọba ma fi mi bin se wa rẹ mi eyin are ololoriwo Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun Igbeyin lodun a haa, Igbeyin lodun a haa Tori alase bimo o, Igbeyin lodun Oluwa Maje ki a de lale YeYe alala kí ọtọ bi mo re, igbeyin lo mo ju o jàre Baba ọlọrun kì é to mo re, igbeyin lo mo ju o jàre Tori Ọba ma fi mi bin se wa rẹ mi eyin are ololoriwo Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun Tori ala lase bimo o, Igbeyin lodun Oluwa Maje ki a de lale Oluwa Maje ka dé o jàre Oluwa Maje ka dé lale Igbeyin lo dun ara ayé o Oluwa Maje ka dé lale Igbeyin lo mo dun kí ọtọ bi mo yin lo jàre Oluwa Maje ka dé lale Iya ọlọmọ toju omo rẹ Igbeyin lodun a haa Igbeyin lodun Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun Tori alase bimo o, Igbeyin lodun Oluwa Maje ki a de lale