Bami wa solution si oro aye mi Bami wa solution si oro aye mi Mase je kope ju Mase je kope ju Ke mi le wa sope Baba onibu ore Edumare onibu ore Baba loke mon ke pe o Bami wa solution soro mi Bami wa solution sile aye mi Gba koso aye mi o baba mimo Eyi oku funmi nile aye mi Jowo dakun lo mi fun ogo re o baba wa Bami wa solution si oro aye mi Bami wa solution si oro aye mi Mase je kope ju Mase je kope ju Ke mi le wa sope Elegede njaye ori e ninu oko Ogbale lo repete Ila iroko re e oba ni nile ikan Igbin ilu koko to fimo tí nu egan Won o lafiwe e rora Ogbo a gidigbi gbogbo ara lo fin sowo Alade mi maa mikan Ohun gbogbo ni sepe Oro le so e o puro Oro le so e o puro o jare Oro le so e o puro Oro le so e o puro o Elegede njaye ori e ninu oko Ogbale lo repete te te te Ila iroko te ri yen oba ni nile ikan o jàre Maa maa wipe Elegede njaye ori e ninu oko Ogbale lo repete Ila iroko re e oba ni nile ikan Igbin ilu koko to fimo ti nu egan Won o lafiwe e rọra Ogbo a girigbi gbogbo ara lo fin sowo Alade mi maa mi kan Ohun gbogbo ni sepe Ohun gbogbo ni sepe Ohun gbogbo ni sepe Ohun gbogbo ni sepe Ohun gbogbo ni sepe Ohun gbogbo ni sepe Ohun gbogbo ni sepe Elegede njaye ori e ninu oko Ogbale lo repete Ila iroko re oba ni nile ikan Igbin ilu koko to fimo ti nu egan Won o lafiwe e rora Ogbo a gidigbi gbogbo ara lo fin sowo Alade mi maa mi kan Ohun gbogbo ni sepe Ina ti e da kii se fun wa rara Ekeye mogbo Efina soko yi ka Akere wo do elefe fi na le jade Ohun ti o le bo si Ohun le nra wo le Elewa titi Oluwa o funyin se Ayanmo o gbogun Ori le le jo Ina ti e da kii se fun wa rara Ekeye mogbo Efina soko yi ka Akere wo do elefe fi na le jade Ohun tí o le bo Si Ohun le nra wole Elewa titi Oluwa o fun yin se Ayanmo o gbogun Ori le le jo Ayanmo o gbogun Ori le le jo Iyen ti daju Ori le le jo Ayanmo o gbogun Ori le le jo Iyen ti yemi ye ke Ori le le jo Sunny Ade maa nki yin o Sunny Ade maa nki yin o Onishola maa nki yin o Onishola maa nki yin o Oni e lowo e bimo Oni e lowo e bimo Oni e sowo e jere Oni e sowo e jere Adeniyi lo nki yin o Agbe tana da nu Atugbe tuntun de Eyi ga ha o ga lagaju e yi ga Agbe tana da nu Atugbe tuntun de e Eyi ga o ga lagaju e yi ga Ema gbo yi ye ni ye yele Yi ye ni ye yele o Ri ro ni ra daba lorun Ayewa kale o jare Nile aiye mi Ayemi loke okun Ayemi nile Naija Ayemi mi lode agbaye Ati nu ile ti mo ngbe Ayemi loke okun Ayemi nile Naija Ayemi lode agbaye Ati nu ile ti mo ngbe Ati nu ile ti mo ngbe Ati nu ile ti mo ngbe Ati nu ebi ti mo ni Ati nu ile ti mo ngbe Ayemi loke okun Ayemi nile Naija Ayemi lode agbaye Ati nu ile ti mo ngbe Agbe tana da nu Atungbe tuntun de Eyi ga o ga lagaju eyi ga Afrikan beat tuntun lagbede Eyi ga o ga lagaju eyi ga Yi ye ni ye yele Riro ni ro adaba lorun Eyi ga o ga lagaju eyiga Oga lagaju eyi ga