Kishore Kumar Hits

King Sunny Ade - Alhaji Chief Okunola Sote текст песни

Исполнитель: King Sunny Ade

альбом: Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide


Lovely (lovely)
Alhaji lovely (lovely)
Obembe l'esu l'esu l'esu l'esu
Obembe l'esu, omo tori ogun waye

Obembe l'esu l'esu l'esu l'esu
Obembe l'esu, omo tori ogun waye

Chief Otun Balogun ano kosi balogun
Kẹṣin keṣe ode nu baba wọn
Bi o dé okan won, kẹṣin k'ẹsẹ
Omo tẹwọgbola, pátákó ẹṣin
Kii je ẹṣin o ṣubu, ṣubu, ṣubu
Kii je ẹṣin o ṣubu
Iru ẹṣin, kii we mo ẹṣin l'orun
Iya eni, bàbá ẹni, kii jo ju oti eni
Pátákó ẹṣin
Kii je ẹṣin o ṣubu, ṣubu, ṣubu
Kii je ẹṣin o ṣubu
Iru ẹṣin, kii we mo ẹṣin l'orun
Iya eni, bàbá ẹni, kii jo ju oti eni
Alhaji lovely (lovely)
Ewọ sìn b'oba gun wa, Olanrewaju Kazeem mi
Alhaji lovely (lovely)
Obembe l'esu l'esu l'esu l'esu
Obembe l'esu, omo tori ogun waye
Okunrole rin, okunrole mi
Okunrole mi o
Chief Okunola mi
Ẹbùn ma gbà bi eyan wa alhaji ṣọtẹ
Baba ni baba n se
Obembe l'esu l'esu l'esu l'esu
Obembe l'esu, omo tori ogun waye
Lovely (lovely)
Alhaji betulah Baba ni baba (lovely)
Executive director Baba (lovely)
Awọn l'alaṣe showkaz Industry (lovely)
Alhaji betulah mi (lovely)
Olanrewaju Kazeem (lovely)
Gbọ mí ni ba dara bami (lovely)
Awore alausa sule mi (lovely)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель