Maajo maa Korin titun Maajo maa Korin titun Bi nba ti ri eni bi eni eyan bi eyan Bi Tolanrewaju Kazeem Maajo o maa korin titun Maajo maa korin titun Maajo maa korin titun Bi nba ti ri eni bi eni eyan bi eyan Bí Tolanrewaju Kazeem Maajo maa korin titun Ebami pe aare kingbo Aare o Lanrewaju njaye e lo were were Eni o dunmo o gbodo so faraye gbo Omo Kazeem naa re o eni re ni Bobagunwa ijebuland Omo ayegbami Omo arigbabuwo Chief Shakiru mi atata Olanrewaju omo Kazeem aguntasholo Araba ni baba eni a ba laba ni baba Chief Bobagunwa gbogbo Ijebuland Chairman jokers industries Original chairman Ijebu Igbo club Omo oloye ayegbami Omo arigbabuwo Iya mo nba ro de Lanrewaju njaye e lo were were Eni o dun mo o gbodo so faraye gbo Omo Kazeem na re o eni re ni Bobagunwa Ijebuland Omo ayegbami Omo arigbabuwo Maa gbadun ni ti e Chief Olanrewaju Kazeem Imule tani imule kabiyesi Oba toto bi aro Oba regbe bi osu Kade pe lori ki bata pe lese oba alase Oba Sikiru Adetona Ogba gba ragba te wole Omo apokusa gere gere laya Araba ni baba eni a ba laba ni baba ni Jebu ode Imule ta ni imule Oba toto bi aro Oba regbe bi osu alaye Oba Adetayo Opakutu baba nile Baba loko ni baba Jebu Igbo mo se ba Kabiyesi alase Lanrewaju maa gbadun ni tire Ko se wu legberun eko A fi aidun o be Baba Marticat, Bisola aya Adepetu londo egi mogun Olowo ori oko Alhaja Rihanat Abeje mama Shafawu Omowale Olowo ori Alhaja Idaya Abike mama Shaki Olatilewa Olowo ori oko Alhaja Kudirat Abeni mamaTaofiki Oladiran Ban ba bu e leyin ma se binu rara rara Ban ba bu e loju e mase binu rara Lanrewaju Agba ti o binu lomo re npo jojo o Ko ma fa si won leti wipe Eyin oju lafe ni Eyin a soro eni leyin Wi fun won pe Eyin oju lafe ni Eyin a soro eni lehin Gbogbo yin le o fori bale fun Lanrewaju Be fe be ko odi tulasi Olarewaju aguntasolo Lanrewaju aguntasolo Epe aare, aare ajagugu Opo aare, aare ejebo oda Aare o pe kogun ma jalu e je a mi Aare o pe kogun ma jalu e je a mi o Oke agbo logun o gbodo ja Aare we lodo gbogbo omode yo wo o se Won ni temi ni o gba Lanrewaju temi ni o gba Shakiru mi omo dara o de jo Shakiru mi omo dara o de jo Nba jo binrin ni nba ti ka e mole Aijo binrin dun mi o nba ti ka e mo de de Bo ya wale ba mi tage kin le bimo to jo e Olarewaju