Kishore Kumar Hits

King Sunny Ade - Constant Star текст песни

Исполнитель: King Sunny Ade

альбом: Sunny Ade and His Green Spot Band, Vol. 4


F'ẹsọ pẹlẹ Babalọla mi
Aye ti le
Ko rọra f'ẹsọ jayé
F'ẹsọ pẹlẹ Babalọla mi
Aye le o
Federal contractor ni
B'aye ba n ba'ni jẹ, b'aye ba n ba'ni mu
Toba ku diẹ ka to
San padà lẹyìn ẹ ni
F'ẹsọ pẹlẹ Babalola mi
Aye le o
Federal contractor o
The president, Babalọla
Ọlayiwọla ni o
Baba Bọlanle
Ọkọ Alhaja Noimot
Ọkọ Alhaja 'keji
Ẹdẹ ni 'le
Ko bami tọju
Husseni Babalọla
Ilọsiwaju ẹgbẹ constant star (Aṣẹ ṣe)
Alhaji Ọmọtayọ Boyiki (Aṣẹ ṣe)
Tijani, oyinbo re leko o (Aṣẹ ṣe)
Adebambọ (Aṣẹ ṣe)
Prince Rẹmi Lagesuru (Aṣẹ ṣe)
Ijabira of Ilanpa o (Aṣẹ ṣe)
Ọmọ Adebeṣin o (Aṣẹ ṣe)
Ọmọ Adams (Aṣẹ ṣe)
Kazeem ni London (Aṣẹ ṣe)
Tijani Bándélé o (Aṣẹ ṣe)
Bayọ, Arẹmu onitemi (Aṣẹ ṣe)
Ọmọ Lawal mi o (Aṣẹ ṣe)
Adekọya omo IK Dairo (Aṣẹ ṣe)
Moshood FM manager (Aṣẹ ṣe)
Nobaga onile ere (Aṣẹ ṣe)
Sikiru igi aje (Aṣẹ ṣe)
Ẹgbẹ constant star (Aṣẹ ṣe)
Ilọsiwaju yẹn o (Aṣẹ ṣe)
Mo juba ọmọ Ẹpẹmolu (Aṣẹ ṣe)
Gbogbo ẹgbẹ constant star (Aṣẹ ṣe)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель