Mo gbọ pọrọ lagbẹdẹ Àgbẹ'dẹ lo n lu rin Mo gbọ garara lagbẹdẹ Àgbẹ'dẹ lo n lu rin Mo gbọ rọmọ òwu lagbẹdẹ Àgbẹ'dẹ lo n lu rin Mo ṣe barakan bi ọmọ ogun mi o The director, Isalẹ Imale trading company Baba Wasiu mi atata, ọkọ Alhaja tiwa ni Oronile padi mi Gbogbo ara ile mi Ẹ ma pèmí l'Akanbi ọgọ ma o Ara ile mi pata Ẹ ma pèmí l'Akanbi ọgọ ma o Akanbi o gọ Oju lọrun ti fú rawa Akanbi o gọ Oju lọrun ti fú rawa Ara ile mi Ẹ ma pèmí l'Akanbi ọgọ ma o Anifowose, la o pe Akanbi o Anifowo', Anifowo' Anifowose la o p'Akanbi o Mama o ma lorukọ meji ti o s'ọmọ Baba o ma lorukọ meji ti o s'ọmọ Anifowo', Anifowo' Anifowose la o p'Akanbi o Akanbi Ogunmi Tijani Sheu Tijani Alhaji Lọla Tijani Sheu Tijani Awọn Alhaji tiwa ni Sheu Tijani Baba ni ẹ ma na Tijani Sheu Tijani Iya ni ẹ ma na Tijani Sheu Tijani