Mo wa ṣe'ba gbogbo agba tin bẹ ni'waju mi dede omo awo patapata Ile ni mo wa (Àní ki Adede gbọ) Irin ajo la wa (Àní ki Adede gbọ) London la wa (Àní ki Adede gbọ) Paper ni mo ka (Àní ki Adede gbọ) Wipe Adeyinka Adebayọ lo tun wa j'oye Major General l'oye tuntun tan gbefun Major General Adeyimika Adebayọ Baba Nikẹ onitemi Baba Gboyega Ọkọ Modupẹ Iye gidi ni'le Major General Major General ọmọ Adebayọ ni Awo Ẹkọ, ọmọ'ba onitemi atata ire London la wa, la wa gbọ wipe Adeyimika Adebayọ ìyẹn lo tu wa j'oye Major General l'oye tuntun tan gbefun Adeyimika (Orire o ni ti ẹ) Adebayọ (Orire o ni ti ẹ) Ọ ṣi ti ṣi f'ọlọrun edumare (Orire o ni ti ẹ) Ma miliki lọ, kò s'ewu rara (Orire o ni ti ẹ) No more people's ti ya were, ko s'ewu l'ẹgbẹrun ọpẹ nu ọbẹ (Orire o ni ti ẹ) Adeyimika Adebayọ mi (Orire o ni ti ẹ) Major General (Orire o ni ti ẹ) Awo Major General Yakubu Gowon ni (Orire o ni ti ẹ) Ọkọ Modupẹ (Orire o ni ti ẹ)