Akure n'ile to l'oye mekun Omo bi d'ale m'ogun erun pa ni Akure l'omi meji, won pe ejeji ala Ala sebire bire, ala d'omi ebo Akure n'ile to l'oye mekun Akure n'ile to l'oye mekun ♪ N'ile ni Barrister Lawyer Faloye mi International Barrister Awon Lawyer r'aja k'aye Ajanaku ti m'igbo kijikijikiji Eda to ba l'ejo, to ba fe gba lawyer Ko lo ri Faloye mi Eda to ba ni case, to ba fe gba lawyer Ko lo ri Faloye mi Barister Lawyer rere Ako n'iwaju adajo A s'ejo e fun e leto leto se o n gbo N'ipari ejo wan a da e lare o Barrister Lawyer l'awa n fe Koja l'eti ri, wan da e lare o Ni gelele ma ba wan debe o jare Akure n'ile to l'oye mekun o N'ile Iasaac Babalola oko Florence Akure n'ile to l'oye mekun o Babalola, baba Olusegun o omo ni Akure n'ile to l'oye mekun o Bank Manager, Babalola mi o ti wa ni Akure n'ile to l'oye mekun o