Everything de de de Talo feku de de de To ba ti bebebe Ki everybody or MD kan penkele mess Ooshey Naira Marley de de de (Marlians) C Blvck de de de Mohbad de de de New generation Marlians de de de Agbo to ta di meyin Agbara lo lo mu wa Aguntan ti o ba japa Imu re a ya Salisu o ti n fagbo Ti iya re ba fi le gbo Won le shepe famugbo Epe o ma ki n mamugbo Hello, Anyways ni na lowo Dido lobo (a do pa) Gbo ti le to ba ti yo Ewo de wa la riwo Iku de de no Gbo mila somo kunrin danu Sho ye ke soro E lo n tu asiri to ye ke bo Oni n fisi, kowole Mofi to si, o yo wole O tin dun mo ko fe lole Ko mo eko, ko mo ona Ile E ba n womo to ni idi Toju eh fine to tun lopon Sholo gbon, wa to gbon To ba mu n gboro wa ko lo gbon O wale mi, mo t'eba fun O n bere ila, temi fe la O n bere efo, temi fe fo O n bere apon, temi le pon Oni n fisi, kowole Mofi to si, o yo wole O tin dun mo ko fe lole Ko mo eko, ko mo ona Ile Kini mo ti ko to n so pe Bobo mohbad yii ma n para Mo shi ma korin tema sodiwuke te ma fori gbara won Omo alara ni mi sha fimile bayii ke mi ma Dara lo Mi o le gbe bon mi o le jale, orin ti mo mo ko, mo ya kanra mo Won lo foro mi l'oyin Set awon tani Set awon hushpuppi ni Abi t'awon Naira Marley ni Ewa na ko kan yin T'eba lo be bi agbo, mo ma kan yin Alaye e foro le Afi te ba nina nile le le mo imole Everything de de de Talo feku de de de To ba ti bebebe Ki everybody or MD kan penkele mess Ooshey Naira Marley de de de (Marlians) C Blvck de de de Mohbad de de de New generation Marlians de de de