Kishore Kumar Hits

9ice - Praise Thee текст песни

Исполнитель: 9ice

альбом: Fear of God


Ahhn (stay with this)
Ẹsẹ' gàn o
Ọlọrun, ẹ ṣe gàn
Ancestor
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omi je mí nu, ẹ ṣe gàn
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omi je mí nu, ẹ ṣe gàn
Bẹ'ṣe ń dùn, ramu-ramu
Ẹyin lẹni kimá fòyà
Eṣu gbo'gun, ole gàn
Ẹyin lẹ lé wọn pá
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omi je mí nu, ẹ ṣe gàn
Haa, Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omi je mí nu, ẹ ṣe gàn
Wọn fẹ kí má rí wọn sá
Wọn ní, kí ń ba rí wọn, kí ń já o
Tí bá ń ri wọn, kí ń ko lu'gbẹ
Emi "ọmọ ase" tí o já, ahh
Wọn gbàgbé pé ẹnì l'Olùwà, kò ní dofo
Wọn gbàgbé pé gbogbo ìlérí Èṣù, lo dofo, (ahh...)
Ẹkorapọ, ké bu mí, kó má dùn mí-
Ẹkorapọ, ké bu mí, kó má dùn mí(ooh)
No weapon fashioned against me shall prosper
Torí mo tí conquer, eh-eh
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omije mí nu, ẹ ṣe gàn
Baba, I go praise Thee
Eyin le nu omije mi nu, ese gan
Be'se n dun, ramu-ramu
Ẹyin lẹni kimá fòyà
Eṣu gbo'gun, o le gàn
Ẹyin lẹ lé wọn pá
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omije mí un, ẹ ṣe gàn, ah
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omije mí un, ẹ ṣe gàn
Al-Rahmani rohimi l'Ọlọrun mí
Al-maliki, Al-kudusi l'Ọlọrun mi
Eletí gbaro ye-
Àla bẹnu, Ọmọ Àsasi
Tiń bá kọkun, àá ṣí
Ọlọrun mí oo, Allah
I just want to praise the Almighty, my Provider
My Guardian, my Witness, my Overseer
Creator, the Maker, Compeller, Restorer, Subduer, Witholder
Extender, Provider
Al-kowi
Aluaa-ali
Al-mumin
Al-mu Katabir
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omije mí un, ẹ ṣe gàn
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omije mí nu, ẹ ṣe gàn
Bẹ'ṣe ń dùn, ramu-ramu
Ẹyin lẹni kimá fòyà
Eṣu gbo'gun, o le gàn
Ẹyin lẹ lé wọn pá
Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu, omije mí nu, ẹ ṣe gàn
Ahh, Baba, I go praise Thee
Ẹyin lẹ nu omije mí nu, ẹ ṣe gàn

(Olumix on the mix)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

Brymo

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель