Kishore Kumar Hits

9ice - Olorun Loni Kori Be E текст песни

Исполнитель: 9ice

альбом: Afro Juju


(Extra Pro)

Ahh, Ọlọ́run lónìí kò rí bẹ'ẹ'
Ọmọ inú mí lo sọ mi dáwo dumate
Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè
Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí
Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè
Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí
Bàbá wà gbo, o tí rí mí, kò tó dá mí
Májẹ k'àyé fọwọ bo'ràwọ̀ mí
Bàbá wà gbo, o tí ríi, kò tó dá mí
Májẹ k'àyé fọwọ bo'ràwọ̀ mí
Tá lọ wà sọ pé kò sí Ọlọ'run? (Tá lọ sọ pé?)
Ènìyàn lo sọ pé kọ sí Ọlọ'run
Tá lọ wà sọ pé kò sí Ọlọ'run? (Táa, tá lọ, tá lo sọ pé?)
Ènìyàn lo sọ pé kọ sí Ọlọ'run
Ahh, Ọlọ́run lónìí kò rí bẹ'ẹ' (kò rí bẹ'ẹ')
Ọmọ inú mí lo sọ mi dáwo dumate
Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè
Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi nídẹ mí (gbémilékè)
Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè
Ìṣòro tó ń di mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí
Bé fẹ, bé kọ, ẹ má gbo ohùn ẹnu mí tọ ń já geere
Má gùn ìyán sínú ọdọ, koto
Máà sebẹ sínú ẹpò ẹpá, ẹni máyo, àáyo
Ọrọ ẹmi at'Ọlọrun láyé mí, kọ ṣe dásí
Láti bí ìpẹpẹ lo ń ṣe bẹ'be, kọ ṣe dásí
Èmí máà kí ẹ
Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè
Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí

(It's Bizzle on the mix)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

Brymo

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель