Kishore Kumar Hits

9ice - Power Must Change Hands текст песни

Исполнитель: 9ice

альбом: Afro Juju


Máà lékè wọn
Má lékè wọn

Má lékè wọn-
(It's Protunez on the beat)
Mo dò ṣí bàtà tí lékè odò o
Ẹjá arọ ń be nísàlẹ odò o
Má f'ẹjá b'orí, gbémilékè wọn
Ìgbàgbọ mí tí mú mi lára dá
Gbogbo àgbára tí yí po padà ahh
Mo tí lékè wọn
Now, I'm grinding, my enemies are crawling
Some dey beside, but never see me coming
My train is nonstop, don't ever try to cross me
Ah, mo tí lékè wọn
I know, power must change hands right now
They know, ẹlẹmi lo má last right now
B'okun o rú, b'ọsa o rú
Ìwọ là má lékè wọn
B'okun o rú, b'ọsa o ru
Àwa là má lékè wọn
Ọmọ to ń pá dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè shana
Ọmọ to ń pá dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lọ lolè shana
Mo kotá, mo kòpée, ọ'tá ń jé
Pé ò gbọ'dọ fohùn
Ọmọ tọ ń pá'wó, tọ ń ṣiṣẹ́
Ò gbọ'dọ májẹ ìgbádùn
Ojú ẹnì má lá, dandan ní arí ìyọnu
Áìfaila ọjo, t'ojo bálá, máa làá
Now, I'm grinding, my enemies are crawling
Some dey beside, but never see me coming
My train is nonstop, don't ever try to cross me
Ahh, mo tí lékè wọn
I know (má lékè wọn), power must change hands right now (ìyá wọn, bàbá wọn)
They know, ẹlẹmi lo má last right now
B'okun ọ rú (b'owó ru), b'oṣa ọ rú (b'owó ru)
Ìwọ là má lékè wọn (à má lékè wọn)
B'okun o rú, b'oṣa o rú
Àwa là má lékè wọn (eh-eh-eeh)
Ọmọ tọ ń pá dán (ọmọ), idán gan-gan idán (kọ má pá dán lo)
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè shana
Ọmọ to ń pá dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lọ lolè shanaa

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

Brymo

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель