Ṣe borí lè já fí ń buja
Orí ẹní lo ń wolé deni
Ti, Anscestor o
Ìbílẹ, milẹ, milẹ, milẹ, milẹ, ti
Ibí t'ẹgbẹ mí tí ń náwó, má jẹ nara ń be o
(Ibí t'egbé mí tí ń kólé) má jẹ kan ra ń bẹ o
I shall never, never work in vain
I shall never, wallow in disgrace
I cancel, I cancel, bad things for my life, I cancel
I cancel, I cancel, ex wey dey make me cry, I cancel
Mo cancel, mo cancel, aṣérì mo cancel
Mo cancel, mo cancel, ìdíbàjẹ́ mo cancel
♪
Wọn ní mo ṣíṣẹ títí, wọn ní kó s'ere
Aje, jọ, fí mí gbàyí, iṣẹ ko lére
Ìṣẹ kọ lówó, témi ye mí, témi ye mí, ahh
Olùwà come bless me without condition
Má fí ìgbàgbọ' mí bá mí wí without solution
Make dem bring confusion with Devil's formation
Ìwọ l'Oluwa mí, perfect solution
I shall never, never work in vain
I shall never, wallow in disgrace
I cancel, I cancel, bad things for my life, I cancel
I cancel, I cancel, ex wey dey make me cry, I cancel
Mo cancel, mo cancel, aṣérì mo cancel
Mo cancel, mo cancel, ìdíbàjẹ́ mo cancel
T'ayé bá ń j'àyé, ta'yé wa ṣì tún ń j'àyè mọ
E mí lẹ o má rí, ohùn mí lẹ o má gbọọ
I lead by grace, so many supplications
Multiply by God's decision
I am a success with global commission
(It's Bizzle on the mix, on the mix)
♪
Tó rí mo tí cancel
Aje tọ jẹe
Поcмотреть все песни артиста