Kishore Kumar Hits

9ice - Otami текст песни

Исполнитель: 9ice

альбом: Afro Juju


(It's Protunez on the beat)
Ẹbilà, ẹbilà
Ẹ yàgò, ẹ yàgò
Ọmọ olóore tí dé, ká lọ
Ìya to jẹ mí o, o gbọ'dọ' jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọ'dọ' tá mí gbé
Ìya to jẹ mí o, o gbọ'dọ' jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọ'dọ' tá mí gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọ'tá òde
Ámónì ṣe ní, ibanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọ'tá òde
Ámónì ṣe ní, ibanidárò
Aṣa ń pekéde bí pé ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ nisẹ lo ń pi-rọrọ
Wọn ní p'oto' o, má lo'to
Wọn ní k'òtò o, má bá wọn bùsi
Mo tí sọ fún wọn tẹlẹ-tẹlẹ pé ẹhìnkulé láṣẹ ní ń gbẹ
Inú'lé tẹrí yẹn, lẹni tí o ń ṣe ẹ wa-aah
O fẹ láyé, ojú ẹ o ní rí, ńkan ló máa f'ọwọ mù
Wọn ọ ṣe ẹ rí, o lọ make e
Wọn gùn ẹ rí, o lọ lókígbe
Wọn yìn ìbọn fún ẹ rí, o lọ layetà
Ìwọ má dírá, o te tàn nìyẹn my brother ah
Ìya to jẹ mí o, o gbọ'dọ' jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọ'dọ' tá mí gbé
Ìya to jẹ mí o, o gbọ'dọ' jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọ'dọ' tá mí gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ibanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ibanidárò
Aṣa ń pekéde bí pé ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ niṣe lo ń pi-rọrọ
Gbogbo òun toju rí kọ lẹnu máa sọ, ọrọ níí
Yára láti gbọ'rọ, lọ'ra láti f'èsì, ọrẹ míì
Wọn fí ẹ ṣọ mí, ọrẹ, jọ, má di monitor
Ò lọ school, jọ, ò kí ńṣe àgùnbanirọ
Nígbà toju pọn mí, ọrẹ, o mọ pé ó jìnà sí mì gann
Àwa náà ré, àti gòkè àti sọọ
Àje Ogungun-nisọ otí bá mí tàn
Ìgbà kàn rí nígbà yẹn, àwa ní janitor
Nísìnyí, ẹni f'ojú àná w'òkú, ẹbọrá áàbolaṣọo
Ìya to jẹ mí o, o gbọ'dọ' jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọ'dọ' tá mí gbé
Ìya to jẹ mí o, o gbọ'dọ' jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọ'dọ' tá mí gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ibanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ibanidárò
Aṣa ń pekéde bí pé ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ nisẹ lo ń pi-rọrọ

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

Brymo

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель