Kishore Kumar Hits

9ice - Murebo текст песни

Исполнитель: 9ice

альбом: Afro Juju


(It's Protunez on the beat)
Àjò to mí re yí o, murebọ o
Àjò to mí re yí o, murebọ o
Àjò tí mo re yí o, má murebọ o
Àjò tí mo re yí o, má murebọ oo-oh
Owó wọlé o, ire dé
Olá wọlé o, ọmọ dé
Ẹlẹgbẹ́ mo ní ẹ jẹ à f'ẹran kọ
Ká fí beer ṣeré pá
Ká fí beer ṣeré pá
Lager beer ṣeré pá, lábé wire, ṣeré pá
Don't be a stupid man o
Life is full of ups and down
If you dey enjoy, brother, appreciate your grace
Àwọn tó ń bẹ nílé, jẹ kàn t'arà rẹ gain
Time to enjoy, brother, make you no dey play
Be'wù b'ẹnlé, má f'olè ṣọ gate
Stop playing!
Àjò to mí re yí o, murebọ o
Àjò to mí re yí o, murebọ o
Àjò tí mo re yí o, má murebọ o
Àjò tí mo rẹ yí o, má murebọ oo-oh
Owó wọlé o, irẹ dé, olá wọlé o, ọmọ dé
Ẹlẹgbẹ́ mo ní è jẹ à f'ẹran kọ
Ká fí beer ṣeré pá
Ká fí beer ṣeré pá
Lager beer ṣeré pá
Lábé wire, ṣeré pá
Òbí, mù'ré wá
Fí yín f'Olùwà, àṣírí yìn lọ ń bẹrẹ sì ńbo
Dem be dey check, but dem dey collect
Who dey checker? Dem go collect
Dem dey spend náírà, we dey spend dollar
Bo ṣe cefa, a má sọdì paper
Ògo Olùwà ní, don't take it personal
I love my beer, odún lénu proper
Stop playing!
Àjò to mí re yí o, murebọ o
Àjò to mí re yí o, murebọ o
Àjò tí mo re yí o, má murebọ o
Àjò tí mo re yí o, má murebọ oh
Owó wọlé o, irẹ dé, olá wọlé o, ọmọ dé
Ẹlẹgbẹ́ mo ní è je à f'ẹran kọ
Ká fí beer ṣeré pá
Ká fí beer ṣeré pá
Lager beer ṣeré pá
Lábé wire, ṣeré pá
(It's Bizzle on the mix)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

Brymo

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель