Kishore Kumar Hits

9ice - Iba текст песни

Исполнитель: 9ice

альбом: Afro Juju


(Speedomile)
Ah-ah!
Milẹ ti, ti, ti
Ah-ah (Skill mix dot com)
Mo júbà Akọdá o (ibà)
Mo júbà Aṣẹ̀dá o (ibà)
Ibà babaláwo (ibà)
Ibà àwọn elẹgbẹ' oo (ibà)
Òpá ká yo láte, Alagogo Ide, iba yín o (ibà)
Ibà tí mo du, kò ṣẹ, kò ṣẹ, kò ṣẹ ní tí lako sẹ
Ẹgbé tí mo níi, wọn ń bẹ, wọn dúró tí mí, wọn je'hùn gbé
Ibà rẹ o, Olódùmarè, ẹni to l'odu, to mobi tí mare eh-eh
Ibà rẹ o
Kíni wọn o fí mí ṣe?
Kíni wọn o fí mí ṣe?
Odigba o ṣe
Àta matáse
Ọmọ ọloto má lo jor (má lo jor)
Ọmọ olófo má p'ofo (má p'ofo)
Òkìtì kàn bí o tí o balaye
Koti-koti fa, bi o ṣe f'araye
Òkìtì kàn bi tí bu b'araye
Òun tí ń kọbi ko bi ni f'arayée
Mo júbà Akọdá o (ibà)
Mo júbà Aṣẹ̀dá o (ibà)
Ibà babaláwo (ibà)
Ibà àwọn ẹlẹgbẹ' oo (ibà)
Ọ'pá ká yo láte Alagogo Ide, ibà yín o (ibà)
Ibà tí mo du, kò ṣẹ, kò ṣẹ, kò ṣẹ ní tí lako ṣẹ
Ẹgbé tí mọ níí, wọn ń bẹ, wọn dúró tí mí, wọn je'hùn gbé
Ibà rẹ o, Olódùmarè, ẹni to l'odu, to mobi tí mare eh-eh
Ibà rẹ o
(It's Bizzle on the mix)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

Brymo

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Eldee

Исполнитель