Kishore Kumar Hits

Olubukunola Bekes - Ologun L' oluwa текст песни

Исполнитель: Olubukunola Bekes

альбом: Mighty God


Ologun loluwa, gbani gbani ma fi ti bon se
Baba alagbara to gba gbara lowo alagbara.
Ogbeni nija keru o boni ja oba alade alafiaa.
Gbogbo ilekun ayeraye
E gbori yin soke
Gbogbo ilekun ailowolowo mo pase
E gbori yin soke
Gbogbo ilekun aibimo
E gbori yin soke
Gbogbo ilekun ailegbadura
E gbori yin soke
Gbogbo ilekun aisefe olorun
E gbori yin soke
Ko ba ogo le wole wa
Oluwa to lagbara julo
Asegun ati ajogun ni a je nipa eje kristi ani isegun boluwa be n fun wa a ki yoo subu ko so ogun to le bori agbara re
Asegun niwa nipa eje jesu, baba fun wa nisegun nipa eje jesu eni ta pa felese sibe o wa o njoba awa ju asegun lo o o, awa ju asegun lo.
Soro saye wa baba
Soro saye wa baba
Baba mimo ja fun mi o
Ja ja ja fun mi o

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители