Kishore Kumar Hits

Brymo - Olúmọ текст песни

Исполнитель: Brymo

альбом: Oṣó


Mo nlọ s'Ake, mo fẹ' lọ rọ'jọ'gbọ'n o
Mo nlo s'Abeokuta, mo fe lọ ri
Omo Soyínka
Osoyinka
Osoyinka
Osoyinka

Be lọ s'Owu
Be ba r'Aremu o
Be ba ri Baba Iyabo, ẹ ba mi ki
Ẹbọra Owu
Ẹbọra Owu oo
Ẹbọra Owu, eeh
Ẹbọra Owu oo

Be lọ s'Abeokuta, ìlo Olúmọ
Bẹ ba r'Alake, ẹ ba mi ki

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Libel

2020 · Мини-альбом

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Jhybo

Исполнитель