Kishore Kumar Hits

Brymo - Olánrewájú - Live текст песни

Исполнитель: Brymo

альбом: Live! At TerraKulture Arena


The next song is called Olánrewájú

Why you think say I wear native come?
Igba o lọ bi orere
Bo ba koro oṣi maa dun ah
Eni to ni suuru kii ṣeyan kekere
Bo ba kan lẹ, oṣi maa goke ah
Boo ba ṣe un tọ fe, won maa kẹyin si e, ẹh a ẹh
Bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ, ẹh a ẹh
Olánrewájú ọmọ ọba
E ma suure da gba
Won ni ko o ṣe were, roora ṣe
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku si bi ọtẹ oo
Olánrewájú ọmọ mi, e ma suure da gba oo
E ma suure da gba
Igba o lọ bi orere
B'ọmọde oku o, oṣi maa da gba
Ṣọra funja, ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ
Oun tio to o, oṣi maa pọ da nu ah
Gbogbo eni abi lo ma ku eh, ẹh a ẹh
Iwa ta a wu lo ma ku ah, ẹh a ẹh
Olánrewájú ọmọ oba, e ma suure da gba o
Won ni ko ṣe were, roora ṣe
E ma suure da gba o
Olooto ko ni ku sibi ọtẹ o
Olánrewájú ọmọ mi, e ma suure da gba o

Olooto ko ni ku sipo ika o
Olooto ko ni ku sibi ote o
Olánrewájú ọmọ ọba, e ma suure dagba o
Olánrewájú ọmọ mi, e ma suure dagba o

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Libel

2020 · Мини-альбом

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель

Jhybo

Исполнитель