Eré òkúta àti gíláàsì Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré Eré òkúta àti gíláàsì Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré Eré òkúta àti gíláàsì Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò Ọlọ'ọ'pá wá o Ẹku owurọ o Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí Wọ'n ní ní òwúrọ' yìí, àwọn ọmọ éèès! Wọ'n ti jà wọ"gboro Wọ'n dẹ' ti ń dáná sunlé Wọ'n ti ń dáná sun oko Àt'ọkọ' ayọ'kẹ'lẹ' àti èyí tí ò yọ'kẹ'lẹ' Gbogbo ẹ' ná ń dáná sun Ẹ gbélé yín o Ẹ ṣọ'ra yín o Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọ'dọ' Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó Kí Ọlọ'run kí ó máa ṣọ' gbogbo wa o Láyọ' o, ẹ ṣé ♪ Ààrẹ ń bọ' l'ájò Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi Orí mi ló gbé mi k'ore Ààrẹ ń bọ' l'ájò Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi Orí mi ló gbé mi k'ore