Mò fí iyẹ' mi fo Mò ri'rè Mò wò waju, mò w'oké Ìrè dé Kí ìjò mọlẹ, mo tún takasúfè O dún mọ mí òó O dún mọ mí òó O dún mọ mí òó òó O dún mọ' mí òó Méjì-méjì làá d'àiyé ò (Méjì-méjì làá d'àiyé ò) Ìfẹ rẹ sí mí, o jìn gángan (Méjì-méjì làá d'àiyé ò) Méjì-méjì làá d'àiyé ò (Méjì-méjì làá d'àiyé ò) Ìfẹ rẹ sí mí, ò jìn gángan (Méjì-méjì làá d'àiyé ò) Ọrẹ, dákun rò kò tó lọ Mò tàràkà, mo ṣubu Kín tó kọ òun món sọ Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì Ẹsìn o gbani Ìwà o lani Òún tó wùn 'nì ló nwa ní ♪ Ọrẹ, dákun rò kò tó lọ Mo tàràkà, mo ṣubu Kín tó mọ òun món sọ Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì Ẹsìn o gbani Ìwà o lani Òún tó wùn'nì ló nwa ni Mó fi iyẹ mí fo Mo rí'rè Mó wò 'wájú, mo w'òkè Ìrè dé Kí ijó mọlẹ, mo tún takasúfè O dùn mọ mí óò O dùn mọ mí óò O dùn mọ mí óò O dùn mọ mí óò Méjì-méjì làá d'àiyé óò (Méjì-méjì làá d'àiyé óò) Ìfẹ rẹ sí mí, o jin gángan (Méjì-méjì làá d'àiyé óò) Méjì-méjì làá d'àiyé óò (Méjì-méjì làá d'àiyé óò) Ìfẹ rẹ sí mí, o jin gángan (Méjì-méjì làá d'àiyé óò) Méjì-méjì làá d'àiyé óò (Méjì-méjì làá d'àiyé óò) Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan (Méjì-méjì làá d'àiyé óò) Méjì-méjì làá d'àiyé óò (Méjì-méjì làá d'àiyé óò) Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan (Méjì méjì làá d'àiyé óọ')