Emi ni, emi l'eni na Okunrin meta ati abo tan fi orin ko Emi ni, emi l'omo na Okunrin merin ati abo, won t'enu mo Mo la'nu, mo soro Mo yo ake, mo foh oro Omo olooforo Mo je akara oforo Emi ni ah, emi ni oh Emi ma l'eni tan soh nigboro Emi ni yaa, emi ni yoo Awon mama gan n' soro ni popo Won lemi l'àkókó Won lemi l'àkókó óh-oh Won lemi l'àkókó óh-oh Won lemi l'àkókó óh-oh Emi ni okunrin na T'awon majesin nso pe m'orin gan Emi ni, emi l'omo na Gbogbo ara adugbo lon t'enu mo Emi baba olowo Mo sh'owo, mo j'ere Iwa ati opolo lon lo Awon ota ti ru po Emi ni ah, emi ni ah Emi ma l'eni ton soh nigboro Emi ni yaa, emi ni yoo Awon omoge n' re'di ni popo Won l'emi l'àkókó (Iwo l'àkókó) Won lemi l'àkókó oh-oh (Iwo l'àkókó oh-oh) Won lemi l'àkókó oh-oh (Iwo l'àkókó oh-oh) Won lemi l'àkókó oh-oh (Iwo l'àkókó oh-oh) Won l'emi l'àkókó (Iwo l'àkókó) Won lemi l'àkókó oh-oh (Iwo l'àkókó oh-oh) Won lemi l'àkókó oh-oh (Iwo l'àkókó oh-oh) Won lemi l'àkókó oh-oh (Iwo l'àkókó oh-oh)