Kishore Kumar Hits

Qdot - Yawu текст песни

Исполнитель: Qdot

альбом: Yawu


Yawu nigbo gbo wa
Qdot l'oruko mi
Ferrari pheragamoe
Yawu ni gbogbo wa
(Kesa sose)
Yawu ni gbogbo wa
Ole fe m'ole (yawu ni gbogbo wa)
Ko se ni to mo bi olorun (yawu ni gbogbo wa)
Awon ara'bi gan gan won jawa l'ole (yawu ni gbogbo wa)
Won ko'wo wa won f'olopa ko wa (yawu ni gbogbo wa)
A fun won lo'be won fe'yin pe'ran o (yawu ni gbogbo wa)
Ole to ba ri mu ni barawo (yawu ni gbogbo wa)
Ise olosho na self employment (yawu ni gbogbo wa)
L'ola sati ramoni, we must to make money
Hustle kowope, without money life is funny
Ninu aye
Ejo to gbo'wo lo o ma kan anybody
Alaye ko k'aye
Obo gbo'wo lo ko ma kan anybody
Yawu ni gbogbo wa
Olosho gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa)
Aboki gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa)
Eh eh, lecturer gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa)
Mr DJ gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa)
Qdot l'oruko mi
A o'le p'ogberi ba'se p'omo awo
Eni t'ile moba sa ni barawo (gbese)
A n'pe l'ole oun gbo'mo eran jo
O logo o loun m'ogogoro
Ejo ti Barca ba ta messi, player melo lo maku
Eni ta gbe pamo to'n wuko
Tori client mi o soro mo
Wo ro pe'la mi oni yomo
Bokan'wo adan mi,adan mi afi rogi
Kosi bo'se fe je,omo ologo ole jegi
Yawu ni gbogbo wa
Ole fe m'ole (yawu ni gbogbo wa)
Ko se ni tomo bi olorun (yawu ni gbogbo wa)
Awon ara'bi gan gan won jawa l'ole (yawu ni gbogbo wa)
Won ko'wo wa won f'olopa ko wa (yawu ni gbogbo wa)
A fun won lo'be won fe'yin pe'ran o (yawu ni gbogbo wa)
Ole to ba ri mu ni barawo (yawu ni gbogbo wa)
Ise olosho na self employment (yawu ni gbogbo wa)
Baba ijebu je mi efon jemi (yawu ni gbogbo wa)
Obo'n ke inoki'n ke (yawu ni gbogbo wa)
Ole to ji maggi lo ma dana sun (yawu ni gbogbo wa)
Eyi to'n gbowo lo wo'n se "Yes sir" fun (yawu ni gbogbo wa)
Pelu motor to'n dun fafun fafun (yawu ni gbogbo wa)
Omo olomo ni o,ema ran le'won o (yawu ni gbogbo wa)
Agba wa mura o se'we ri (yawu ni gbogbo wa)
Olode ologun ologbon lo'lode o (yawu ni gbogbo wa)
Edakun ejo ka tun'wa ara wa se o (yawu ni gbogbo wa)
Awon ka'n ka pata lo tokun tokun (yawu ni gbogbo wa)
"Baby I love you" na scam o (yawu ni gbogbo wa)
Kesa sose gbese soke (yawu ni gbogbo wa)
Awon eyan sirikuma sirikuma (yawu ni gbogbo wa)
Owo mi da o (yawu ni gbogbo wa)
Artist,DJ,dancer,bouncer (yawu ni gbogbo wa)
Show promoter, kara kata (yawu ni gbogbo wa)
Yawu ni gbogbo wa

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

Kashy

Исполнитель

Kabex

Исполнитель

Lyta

Исполнитель