Kishore Kumar Hits

Qdot - Magbe (feat. Patoranking) текст песни

Исполнитель: Qdot

альбом: Alagbe


Magbé oh, magbé (2T upon the beat)
Magbé oh, magbé (Whatyasay?)
Magbé oh, magbé
(Qdot lórúkọ mí) magbé oh, magbé
Magbé oh, magbé
Magbé oh, magbé (magbé, magbé o)
Magbé oh, magbé
Magbé oh, magbé
Magbé oh, magbé
Ọmọ oloja, magbé oh, magbé
Magbé oh, magbé
Ọmọ oloja, magbé oh, magbé
Logan tó wo'ra (magbé)
Logan lo ṣíṣẹ (magbé)
Logan tó ṣíṣẹ
Lo ṣ'ojú yaman-yaman (kúrò nbẹ yẹn na, magbé)
Logan tó wo'ra (magbé)
Logan lo ṣíṣẹ (magbé)
Logan to ṣíṣẹ lo ṣ'ojú yaman-yaman
À ran'mọ ní dodo, ó ra Colorado
Ó ra panadol, ó ra tramadol, ah
Ṣerí pé, ó lo far
Ewé ewedu, no be ewé cocoa
Kòsí fẹyin wo ní Idiroko
Ẹ wá wo adifa, tó f'oja d'ifa
Ifá pé Kafaya ní Wiz Khalifa
Àwa èwe, a fẹ rán ewé (ewé)
T'aba tí rí oluwe (mawe)
T'ẹ'mí rẹ ó bà gbé, málọ bà wọn ṣé àfarawé s'ewé
Magbé oh
Agege, magbé oh (magbé)
Magbe oh
Ebute Metta, magbé oh (magbé)
Magbe oh
Ọmọ oloja, magbé oh (magbe)
Ọmọ t'oba gbé, ó mà dí gobe
Kele magbé, gbé
Igi gogoro mà gún mi lójú
At'òkè là má tí wo
K'eba to jìnà kan'lẹ dádá, orí'na là má tí ro
Àjà ń sáré, owó ń jo'na
Kafaya padà fi'di jo'na
Ọmọ uni', ọmọ poli'
Málọ gbé chemical, málọ gbé kpoly
Another person girl (magbé)
Another person beer (magbé)
Mummy tellin' them (magbé)
Ọtí ọlọti ní (magbé)
Another person girl (magbé)
Another person beer (magbé)
Mummy tellin' them (magbé)
Ọtí ọlọti ní (magbé)
(Whatyasay?)
Magbé oh, magbé
Ọmọ oloja, magbé oh, magbé
Magbé oh, magbé
Ọmọ oloja, magbé oh, magbé
Logan tó wo'ra (magbé)
Logan lo ṣíṣẹ (magbé)
Logan tó ṣíṣẹ
Lo ṣ'ojú yaman-yaman (kúrò nbẹ yẹn na) (magbé)
Logan tó wo'ra (magbé)
Logan lo ṣíṣẹ (magbé)
Logan to ṣíṣẹ to ṣ'ojú yaman-yaman
Ṣ'ẹlẹyà mummy, ṣ'ẹlẹyà daddy
Ẹ wo b'ẹṣe ń ṣé, ayy
Bàbá lo gbé
Ẹdi mú kótó wo general market oh
Àwa èwe, à fẹ́ràn ewé (ewé)
T'ábà tí rí olúwé (mawe)
T'ẹ'mí rẹ ó bà gbé, málọ bà wọn ṣé àfarawé s'ewé
Rọra gbé oh, rọra gbé
Ó bà ṣàánú momo rẹ
Ọmọ loja rọra mágbé
Gbọ'rọ Olúwa
Da-da-da-da-da
Da-da-da-da-da
Da-da-da-da-da
Da-da-da-da-da
2T on the Mix

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

Kashy

Исполнитель

Kabex

Исполнитель

Lyta

Исполнитель