Apata Aiyeraye se ibi isa di mi Je ki omi oun eje To san lati iha re To sa lati iha re Se iwosan fe se mi Apata Aiyeraye se ibi isa di mi Je ki omi oun eje To san lati iha re To sa lati iha re Se iwosan fe se mi Ko sohun ti mo muwa Mo romo agbelebu Igi oro, igi iya Ta kan olugbala mo Laikun, lai sawawi Bi aguntan ni waju olu rerun Oyadi ko ti le fohun Oku fun te mi ti re Apata Aiyeraye se ibi isa di mi Je ki omi oun eje To san lati iha re To sa lati iha re Se iwosan fe se mi Iku oro lori igi, oko egbe, oti kikan Wonyi niya ti olugbala je Nitori temi tire Iwo yo tun kan mo gi bi? Pelu ise ati iwa owo re Ronu piwada, ko ese sile Ka ri o sinu ife baba Apata Aiyeraye se ibi isa di mi Je ki omi oun eje To san lati iha re To sa lati iha re Se iwosan fe se mi Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Abi owo loun wa Ore mi figbagbo gbe Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Omo loun wa Eyi lo n dun o lokan Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Owase wa se, o ri se So nigbagbo Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi O nile lori, Abonile yo e lenu Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Ki loun to n dun o lokan To le bore so Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Bere gbe, Bere gbe, Bere gbe, Bere gbe Afuye Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Fayo gbe, Fayo gbe, Fayo gbe, Fayo gbe Afuye Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Gbe agbelebu re Bo wu wo bi ko wu wo Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi Ma to jesu lehin Ko bo ninu ebi