Angeli ewole fun Emu ade oba re wa Se l'oba awon oba Ti npe ni pepe re Gbe gbongbo igi, jesse ga Se l'oba awon oba Ti a ti rapada Eki eni t'o gba yin la, Se l'oba awon oba Ranti banuje yin Ete 'kogun yin sese re Se l'oba awon oba Ni gbogbo agbaye Ki won ki, "kabiyesile Se l'oba awon oba Lati ma juba re K'a bale jo jumo korin Se l'oba awon oba