OLORUN IGBALA Olorun igbala mo sadi oo Olorun iwosan, mo kepe o baba Dina memi okunkun maje kan le bori okan mi oo Agbara satani atomo ogun re mani ko da san Ba satani wi layemi Edumare mo be o ye Ma se jeki satani raye wonu okan mi Mo gbe jomi to o wa Jesu sanu funmi Mo gbe jomi to o wa Jesu gboro mi ro B'emi okunkun ba parapo to bawa fejomi sun oo Tejere ni koro baba ko fi dami la re Back to chorus Sambalati nbe laye Tobiah be Iran Judasi ko tan late Nse lo ye ka fun ra Ero buburu tamani ro Lori Modekai Gbogbo re lo dasan Ise Oluwa ni Ero buburu tamani gba Lori Modekai Gbogbo re lo dasan Igbega lo yori so Bemi okunkun ba parapo To ba wa fejo mi sun T'eje Re ni ko ro Baba Ko fi damilare Ibi esu ba gon si Ninu ile mi too Ibi esu ba gon so Lori ise mi o Agbara No Mercy Baba fi rojo ina le lori Satani Oluwa nba o wi pe ko dehin lehin mi Dehin, dehin satani dehin lehin mi o Dehin