Omo o ba ma j'aye ori re l'ode Ojo mbo wipe o ni le lo'gba Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye Omo o ba ma s'ise owo re l'odo o Igba mbo kankan o ni le lakaka Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye Omo o ba ma j'aye ori re l'ode Ojo mbo wipe o ni le lo'gba Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye Omo o ba ma s'ise owo re l'odo o Igba mbo kankan o ni le lakaka Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye Se'untoose ore ojo nlo o Se'untoose ore ojo nlo o Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni Amose o d'oro eda ni gbe ni Ani o Se'untoose ore ojo nlo o Ani o Se'untoose ore ojo nlo o Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni Amose o d'oro eda ni gbe ni Omo o ba ma j'aye ori re l'ode Ojo mbo wipe o ni le lo'gba Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye Omo o ba ma j'aye ori re l'ode Ojo mbo wipe o ni le lo'gba Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye Se'untoose ore ojo nlo o Ani o Se'untoose ore ojo nlo o Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni Amose o d'oro eda ni gbe ni ore o Ani o Se'untoose ore ojo nlo o ye ye ye Se'untoose ore ojo nlo o Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni Amose o d'oro eda ni gbe ni ore o Omo o ba ma j'aye ori re l'ode Ojo mbo wipe o ni le lo'gba Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye Omo o ba ma sise owo re l'ode Egba mbo kan kan o ni le lakaka Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri Oba je a lo'gba yi pe o l'aye.