Mo r'óhun tó wùn mí, arárọ'mí Ẹlẹ'yinjú ẹgẹ', onítèmi, arẹwà Ìgbàmíràn t'ó rẹ' mí o, t'ó fẹ' sú mi yé o Ma ṣe 'rántí ẹ'rín rẹ, ma tú'ra ká o Mo mà r'óhun tó wùn mí o, arádẹ'mí Afẹ'rínpanáọ'tẹ', ọlọ'rọ' mi ọmọ ọlà Ìgbàmíràn t'ó rẹ' mí o, t'ó fẹ' sú mi Ma rántí àwọn ọ'rọ' rẹ, ma tún 'ra mú o Wá'lé, wá'lé olólùfẹ' jọ'wọ' o Dúró, ká jọ máa lò'gbà yì' o Wá'lé, wá'lé aládùnní baby o Dúró, ká jọ máa lò'gbà yì' o