Bó sáré ma fò o, bó dẹ rìn, ma sáré (Bó sáré ma fò o, bó dẹ rìn, ma sáré) Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọbọ Bó wọ'lé ma lòṣó o, ma dèrìgì pẹ̀lú eléyín (Bó wọ'lé ma lòṣó o, ma dèrìgì pẹ̀lú eléyín) Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọbọ Wọlé o bá nmú ńkan mí (gbèsè rẹ ni o máa sán) ♪ Gbèsè rẹ ni odẹ máa sán ♪ (Gbèsè rẹ ní o máa sán) ♪ Gbèsè rẹ ni òdẹ máa sán ♪ Bó pọn'gi ma tèle, bo wè'kun, ma wọ'nú ibú (Bó pọn'gi ma tèle, bo wè'kun, ma wọ'nú ibú) Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á se bí ọbọ Bó mú 'nú aginjù lọ, ma fi ìgboyà wọ'nú igbó (Bó mú 'nú aginjù lọ, ma fi ìgboyà wọ'nú igbó) Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọbọ Wọlé o bá ńmú ńkan mi (gbèsè rẹ ní o máa sán) ♪ Gbèsè rẹ ni odẹ máa sán ♪ (Gbèsè rẹ ní o máa sán) ♪ Gbèsè rẹ ni odẹ máa sán ♪ Gbèsè rẹ ni o máa sán!