Ojú funfun kọ' nì'wà ire Bara dúdú kọ'rọ'í, é mà í ṣe t'àìwe Akáwọgbékùn tó ń wòye kì mà í ṣ'ọ'lẹ Ṣèbí'nú ló ń rò (Inú ló ń rò) Mo sèbí'nú ló ń rò A kó'ra jọ ń wùwà ibi, tìfunlọ'ràn, wọn ò l'ọ'nà méjì Ilé à gbé f'ọ'bùn láti ṣọ', bí ò bá dàwó, ìgbẹ' ni yó dì Igbó ń lá ni yó dà Moni, ìgbẹ' ni yó dì ♪ Áàrí jẹ, rí mú, rántí ailani Ẹní tí ń wọṣọ ńlá, rántí oníhòòhò Àwaayé mọyà, má gbàgbé, pé a ó mo' òun wá À o ní di lọ (À òní ko kàn lọ) À o ni di lọ Ayáraṣàṣà, ìyẹn lè sá'ré g'òkè Onísùúrù, ìyẹn á dé'bẹ' dandan, dandan Ọlọ'gbọn ayé, ìyẹn ń wòye kì mà í ṣọ'lẹ Ṣèbí'nú ló ń rò (Inú ló ń rò)