Ní kùtù l'ówù'rọ' o, bẹ'ẹ jí ẹ ó ri l'ọ'nà B'ọ'jọ' bá ti là, kìí fi'ṣẹ' rẹ' ṣe'ré Ọmọ Akin tí nwù'wà àgbà, ọmọ àgbà tí nṣ'ìṣe ọgbọ'n Ọmọ ọkọ tí ò rẹ'wẹ'sì, iṣu rẹ' l'ó mà jiná Ará ẹ má jowú rẹ', iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o Aiyé ẹ má ran'jú mọ, iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o ♪ Owó dùn ná, mo mọ' o, mo mọ o, mo mọ Iṣẹ' ni ò dùn ṣe lójò-lẹ'rùn Ọládùnní, mo mọ' o, mo mọ' o, mo mọ Iṣẹ' ni ò dùn ṣe kárakára Àlá tí ò l'ẹ'sẹ' ìtàn làáfi pa, èrò tí ò di ìṣe àròkàn ọjọ' alẹ' Ẹ yé ẹ'yin ọ'dọ' wa, ẹ gbé'ra ní'lẹ' mú'ṣẹ' ṣe o ♪ Ẹ má wo b'ó ti rí o, ẹni nke're ń bọ' wá kó're ayọ' ♪ Ká f'ọlá f'ọ'lọ'lá, l'óde, ló yẹ, ló yẹ Gb'ádé f'ẹ'ni tó yẹ láì w'ọjọ' orí Ọmọ Akin tí nwù'wà àgbà, ọmọ àgbà tí nṣ'ìṣe ọgbọ'n Ọmọ Akin tí ò rẹ'wẹ'sì, iṣu rẹ' l'ó mà jiná Ará ẹ má jowú rẹ' o, iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o ♪ Aiyé ẹ má fẹ'jú mọ, iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o Ẹ'yin ọ'rẹ' ẹ má bínú si, iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o Ará ẹ má jowú rẹ', iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o Aiyé ẹ má ran'jú mọ, iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o Ẹbí e ma bínú sí, iṣẹ' ọwọ' rẹ' ló mí jẹ o