Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Oloja текст песни

Исполнитель: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

альбом: Amunudun


Mo k'áwo s'ọ'jà nṣ'ajé
Agbéwiri f'ẹ'sọ' kó wọn lọ
Ó l'ọ'ba ló mà rán 'un ní'ṣẹ' olè
Ojú mi pàkò nwòran
A gb'ọ'kà sí'lẹ' ká jẹun (ká fi'un sínú)
Ọlọ'bùn yí pẹ'tẹ' k'ọ'wọ' sí'nú rẹ' (pọ'ṣọ'pọ'ṣọ')
Abọ'nisíhòhò tí nf'ewé bo tirẹ'
Ẹnu mi sùtì ò r'ọ'rọ' sọ
Onísùúrù é mà í ṣe t'ọ'dẹ' o
Àní ka má jà ló jù o
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, oh
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni, ye o
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni, ye o
A gbé'lù sí'lẹ' ká ṣe'ré
Wọn l'áwọn l'ó kàn láti jó l'ágbo
Ẹlẹ'sẹ' mẹ'rìnlá fi mú fọn fèrè
Etí mi fẹ'nfẹ' ò f'áriwo
Onísùúrù é mà í ṣe t'òmùgọ' o
Àní ka má jà ló jù o
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, oh
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni o, ye o
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, (enu mi sùtì ò r'ọ'rọ' sọ)
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni o (etí mi fẹ'nfẹ' ò f'áriwo)
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, oh
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni o, ye o
Ha-ha-ha-ha, yé Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, (enu mi sùtì ò r'ọ'rọ' sọ)
Ha-ha-ha-ha

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители