"Onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bẹbẹ Wọ'n l'óun t'ó ti gbé ṣe, ó mà tóbi o L'ọ'jọ' ọjọ' yẹn, ó ṣe kísà, ó ná'wó ná'ra Ọ'nà rèé, kálọ ká fi hàn ọ'" La'jú rẹ sílẹ' ko r'ẹ'yìn atanijẹ La'tí rẹ sílẹ', ko gbọ"rọ' òtítọ' nì Ẹni nṣ'ọdún owó yẹn, ṣ'ó l'áyọ' nínú? Gbogbo oun tó ndán kọ' ni wúrà o Jọ'wọ' m'ọ'wọ' rẹ sí're ọ'rẹ', ṣè'wọ'n t'ápá rẹ bá ká àbúrò Má ṣe wù'wà ìbàjẹ', má ṣe k'ẹ'gbẹ' ọlọ'tẹ' Ọ'nà tóró yẹn ló l'ádùn gan Jọ'wọ' m'ọ'wọ' rẹ sí're ọ'rẹ', ṣè'wọ'n t'ápá rẹ bá ká àbúrò Má ṣe mọ'dàrú, má ṣe k'ẹ'gbẹ' ọlọ'bùn Ìwà rere yẹn ní f'ọkàn ẹni ba'lẹ' Àgbà sọ fún wa ní'gbà ọ'dọ' o, ẹni ire Wọ'n ló yẹ k'ọ'mọlúàbí ní ìtẹ'lọ'rùn Ká má fì 'ka mẹ'wà' jẹun lẹ'ẹ'kan T'àìgbọ'n kọ' ni ká ṣe pẹ'lẹ' Ẹni l'ọ'lá ìyẹn á mà bá'lẹ' lọ Ẹni ò ní kò ní kọjá ọjọ' tirẹ' Ká má ṣe bí ọlọ'rọ' tó gbàgbé ọgbọ'n Ìwa tó dára ló ga jù o Jọ'wọ' m'ọ'wọ' rẹ sí're ọ'rẹ', ṣè'wọ'n t'ápá rẹ bá ká àbúrò Má ṣe wù'wà ìbàjẹ', má ṣe k'ẹ'gbẹ' ọlọ'tẹ' Ọ'nà tóró yẹn ló l'ádùn gan Jọ'wọ' m'ọ'wọ' rẹ sí're ọ'rẹ', ṣè'wọ'n t'ápá rẹ bá ká àbúrò Má ṣe mọ'dàrú, má ṣe k'ẹ'gbẹ' ọlọ'bùn Ìwà rere yẹn ní f'ọkàn ẹni ba'lẹ' M'ọ'wọ' rẹ sí're ọ'rẹ', ṣè'wọ'n t'ápá rẹ bá ká àbúrò Má ṣe wù'wà ìbàjẹ', má ṣe k'ẹ'gbẹ' ọlọ'tẹ' Ọ'nà tóró yẹn ló l'ádùn gan Jọ'wọ' m'ọ'wọ' rẹ sí're ọ'rẹ', ṣè'wọ'n t'ápá rẹ bá ká àbúrò Má ṣe mọ'dàrú, má ṣe k'ẹ'gbẹ' ọlọ'bùn Ìwà rere yẹn ní f'ọkàn ẹni ba'lẹ' Onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bẹbẹ Ah, onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe rere Ah, onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bebe Onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe dada Onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bebe Onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe rere